Ku ise Lyrics By Psalmos

Ku ise Lyrics By Psalmos
Instrumental…….
mo wo waju mi mo ri owo yin
mo wo eyin wo mo ri ife yin
won wa bere lo wo mi pe bawo ni mo se se
mo so fun won wipe eeeeee

Solo:
(emi na ko o olorun oba ma ni
olo run oba ma ni
olorun oba ma ni) 2x
Chorus:
(moni baba kan oo
moni baba kan ooo
baba ara to mo iyi omo) 6x
oluwa ku ise
ehhh ehhhh ehhhh
ku isee…
ehhh ehhhh ehhhh
ku isee…
oooooooooo
oluwa ku ise oooo
ehhh ehhhh ehhhh
ku isee…
oni ko bi o su bu mo ro bi oo (elo o se ye)
eterete ooo baba ku ise…(elelele jare bio ) 3x
(oluwa ku ise
iba mi ku ise) 2x
ku ise 5x
oni ko bi o su bu mo ro bi oo
eterete ooo baba ku ise) 3x
mo de wa so pe
ni mo de wa so pe oo) 2x
o ni kan she lo ore ire bo….
orun bi o ni…..
emi kan se lore iwo nbo…
mo de ya so pe oooo ehhh.
interlude:
eyin bi olode o ba ku
oju ide re kin ru ikoriko
ko sa aseyin olubori
ato fi arati bi oke
ti emi
a le mi no emi
ti mo fi goke odo afara tanja
ara efi oju ire wo mi
eniya efi owo anu kan mi
emi na ko..
eledumare ni
olorun mi ahhh
baba mi
eledumare
ogba gba ti gba alara ilara
oba aa ji ki
oba aa ji rii
ehhh eyin
ehhh beeee
chorus:
oni ko bi o su bu mo ro bi oo
eterete ooo baba ku ise
interlude
oni kan wi o subu (maro guro ehhh)3x
oooo…. ooooooooooo
3 Comments
Posted in Uncategorized
Tagged ku ise, oluwa, wa ju
ALSO SEE  Hero Lyrics – Tim Godfrey & D Xtreme Crew

NgLyrics Editor

NgLyrics Editor is the chief among the editorial team of New-age Gospel Lyrics. Our team is made up of dedicated believers around the world whose sole interest is promoting the gospel via songs, worship, messages and praise. You can join our team of contributors by sending us a contact request